Gẹnẹsisi 10:23
Genesis 10:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Aramu ni: Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki.
Genesis 10:23 in English
Genesis 10:23 · Berean Standard Bible
The sons of Aram: Uz, Hul, Gether, and Mash.*
Context
21A bí àwọn ọmọ fún Ṣemu tí Jafeti jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin: Ṣemu sì ni baba gbogbo àwọn ọmọ Eberi. 22Àwọn ọmọ Ṣemu ni:
Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. 23Àwọn ọmọ Aramu ni:
Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki. 24Arfakṣadi sì bí Ṣela,
Ṣela sì bí Eberi. 25Eberi sì bí ọmọ méjì:
ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.