Gẹnẹsisi 10:22
Genesis 10:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu.
Genesis 10:22 in English
Genesis 10:22 · Berean Standard Bible
The sons of Shem: Elam, Asshur, Arphaxad, Lud, and Aram.
Context
20Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Hamu, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, àti èdè wọn, ní ìpínlẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn. 21A bí àwọn ọmọ fún Ṣemu tí Jafeti jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin: Ṣemu sì ni baba gbogbo àwọn ọmọ Eberi. 22Àwọn ọmọ Ṣemu ni:
Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. 23Àwọn ọmọ Aramu ni:
Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki. 24Arfakṣadi sì bí Ṣela,
Ṣela sì bí Eberi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.