Esekiẹli 21:17
Ezekiel 21:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi gan an yóò pàtẹ́wọ́ ìbínú mi yóò sì rẹlẹ̀. Èmi Olúwa ti sọ̀rọ̀.”
Ezekiel 21:17 in English
Ezekiel 21:17 · Berean Standard Bible
I too will strike My hands together, and I will satisfy My wrath.’ I, the LORD, have spoken.”
Context
15Kí ọkàn kí ó lè yọ́
kí àwọn tí ó ṣubú le pọ̀,
mo ti gbé idà sí gbogbo bodè fún ìparun.
Háà! A mú kí ó kọ bí ìmọ̀nàmọ́ná,
a gbá a mú fún ìparun. 16Ìwọ idà, jà sí ọ̀tún
kí o sì jà sí òsì
lọ ibikíbi tí ẹnu rẹ bá dojúkọ. 17Èmi gan an yóò pàtẹ́wọ́
ìbínú mi yóò sì rẹlẹ̀.
Èmi Olúwa ti sọ̀rọ̀.” 18Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ mi wá: 19“Ọmọ ènìyàn la ọ̀nà méjì fún idà ọba Babeli láti gbà, kí méjèèjì bẹ̀rẹ̀ láti ìlú kan náà. Ṣe àmì sí ìkóríta ọ̀nà tí ó lọ sí ìlú náà.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.