Native Bible

Ezekiel 19:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Kọ orin ọ̀fọ̀ nítorí àwọn ọmọ-aládé Israẹli

Ezekiel 19:1 in English

Ezekiel 19:1 · Berean Standard Bible

“As for you, take up a lament for the princes of Israel

Context

1“Kọ orin ọ̀fọ̀ nítorí àwọn ọmọ-aládé Israẹli 2wí pé: “ ‘Èwo nínú abo kìnnìún ni ìyá rẹ̀ ní àárín àwọn kìnnìún yòókù? Ó sùn ní àárín àwọn ọ̀dọ́ kìnnìún ó sì ń tọ́jú àwọn ọmọ rẹ̀. 3Ó sì tọ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ dàgbà, ó sì di kìnnìún tó ní agbára, ó kọ́ ọ láti ṣọdẹ, ó sì ń pa àwọn ènìyàn jẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.