Esteri 7:1
Esther 7:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọba àti Hamani sì lọ sí àpèjẹ pẹ̀lú Esteri ayaba,
Esther 7:1 in English
Esther 7:1 · Berean Standard Bible
So the king and Haman went to dine with Esther the queen,
Context
1Ọba àti Hamani sì lọ sí àpèjẹ pẹ̀lú Esteri ayaba, 2bí wọ́n sì ṣe ń mu wáìnì ní ọjọ́ kejì yìí, ọba sì tún béèrè pé, “Esteri ayaba, kí ni ẹ̀bẹ̀ rẹ? A ó sì fi fún ọ. Kí ni ìbéèrè rẹ? Bí ó tilẹ̀ jẹ́ ìdajì ìjọba à mi, n ó fi fún ọ.” 3Nígbà náà ni ayaba Esteri dáhùn, “Bí èmi bá rí ojúrere rẹ, ìwọ ọba, bí ó bá sì tẹ́ ọláńlá à rẹ lọ́rùn, fún mi ní ẹ̀mí mi, èyí ni ẹ̀bẹ̀ mi. Kí o sì pa àwọn ènìyàn mi mọ́—èyí ni ìbéèrè mi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.