Oniwaasu 11:2
Ecclesiastes 11:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Fi ìpín fún méje, àní fún mẹ́jọ pẹ̀lú, nítorí ìwọ kò mọ ohun ìparun tí ó le è wá sórí ilẹ̀.
Ecclesiastes 11:2 in English
Ecclesiastes 11:2 · Berean Standard Bible
Divide your portion among seven, or even eight, for you do not know what disaster may befall the land.
Context
1Fún àkàrà rẹ sórí omi,
nítorí lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, ìwọ yóò rí i padà. 2Fi ìpín fún méje, àní fún mẹ́jọ pẹ̀lú,
nítorí ìwọ kò mọ ohun ìparun tí ó le è wá sórí ilẹ̀. 3Bí àwọsánmọ̀ bá kún fún omi,
ayé ni wọ́n ń rọ òjò sí.
Bí igi wó sí ìhà gúúsù tàbí sí ìhà àríwá,
níbi tí ó wó sí náà, ni yóò dùbúlẹ̀ sí. 4Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń wo afẹ́fẹ́ kò ní fúnrúgbìn;
ẹnikẹ́ni tí ó bá ń wo àwọsánmọ̀ kò ní kórè.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.