Native Bible

Daniel 5:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Èyí ni nǹkan tí ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí: “Mene: Ọlọ́run ti ṣírò ọjọ́ ìjọba rẹ. Ó sì ti mú u wá sí òpin.

Daniel 5:26 in English

Daniel 5:26 · Berean Standard Bible

And this is the interpretation of the message: MENE * means that God has numbered the days of your reign and brought it to an end.

Context

24Nítorí náà, ó rán ọwọ́ tí ó kọ àkọlé yìí. 25“Èyí ni àkọlé náà tí a kọ: Mene, mene, tekeli, peresini. 26“Èyí ni nǹkan tí ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí: “Mene: Ọlọ́run ti ṣírò ọjọ́ ìjọba rẹ. Ó sì ti mú u wá sí òpin. 27“Tekeli: A ti gbé ọ lórí òsùwọ̀n, ìwọ kò sì tó ìwọ̀n. 28“Peresini: A ti pín ìjọba rẹ a sì ti fi fún àwọn Media àti àwọn Persia.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.