2 Samuẹli 22:19
2 Samuel 22:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n wá láti borí mi lọ́jọ́ ìpọ́njú mi, ṣùgbọ́n Olúwa ni aláfẹ̀yìntì mi.
2 Samuel 22:19 in English
2 Samuel 22:19 · Berean Standard Bible
They confronted me in my day of calamity, but the LORD was my support.
Context
17“Ó ránṣẹ́ láti òkè wá, ó mú mi;
ó fà mí jáde láti inú omi ńlá wá. 18Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi alágbára,
lọ́wọ́ àwọn tí ó kórìíra mi, nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ. 19Wọ́n wá láti borí mi lọ́jọ́ ìpọ́njú mi,
ṣùgbọ́n Olúwa ni aláfẹ̀yìntì mi. 20Ó sì mú mi wá sí ààyè ńlá,
ó gbà mi, nítorí tí inú rẹ̀ dún sí mi. 21“Olúwa sán án fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi;
ó sì san án fún mi gẹ́gẹ́ bí mímọ́ ọwọ́ mi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.