Native Bible

1 Thessalonians 5:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ fi ìfẹ́nukonu mímọ́ ki ara yin.

1 Thessalonians 5:26 in English

1 Thessalonians 5:26 · Berean Standard Bible

Greet all the brothers with a holy kiss.

Context

24Olóòtítọ́ ni ẹni tí ó pè yín, yóò sì ṣe. 25Ẹ̀yin ará, ẹ gbàdúrà fún wa. 26Ẹ fi ìfẹ́nukonu mímọ́ ki ara yin. 27Mo pàṣẹ fún yín níwájú Olúwa pé, kí ẹ ka lẹ́tà yìí fún gbogbo àwọn ará. 28Ki oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa, wà pẹ̀lú yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.