1 Tẹsalonika 5:25
1 Thessalonians 5:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ̀yin ará, ẹ gbàdúrà fún wa.
1 Thessalonians 5:25 in English
1 Thessalonians 5:25 · Berean Standard Bible
Brothers, pray for us as well.
Context
23Kí Ọlọ́run fúnra rẹ̀, Ọlọ́run àlàáfíà, sọ yín di mímọ́ pátápátá. Kí Ọlọ́run pa ẹ̀mí àti ọkàn pẹ̀lú ara yín mọ́ pátápátá ní àìlábùkù, títí di ìgbà wíwá Jesu Kristi Olúwa wa. 24Olóòtítọ́ ni ẹni tí ó pè yín, yóò sì ṣe. 25Ẹ̀yin ará, ẹ gbàdúrà fún wa. 26Ẹ fi ìfẹ́nukonu mímọ́ ki ara yin. 27Mo pàṣẹ fún yín níwájú Olúwa pé, kí ẹ ka lẹ́tà yìí fún gbogbo àwọn ará.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.