Native Bible

1 Thessalonians 5:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ki oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa, wà pẹ̀lú yín.

1 Thessalonians 5:28 in English

1 Thessalonians 5:28 · Berean Standard Bible

The grace of our Lord Jesus Christ be with you.*

Context

26Ẹ fi ìfẹ́nukonu mímọ́ ki ara yin. 27Mo pàṣẹ fún yín níwájú Olúwa pé, kí ẹ ka lẹ́tà yìí fún gbogbo àwọn ará. 28Ki oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa, wà pẹ̀lú yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.