1 Ọba 7:44
1 Kings 7:44 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
agbada ńlá náà, àti màlúù méjìlá tí ó wà lábẹ́ rẹ̀;
1 Kings 7:44 in English
1 Kings 7:44 · Berean Standard Bible
the Sea; the twelve oxen underneath the Sea;
Context
42irinwó (400) pomegiranate fún iṣẹ́ àwọn méjì, ọ̀wọ́ méjì pomegiranate fún iṣẹ́ àwọn kan láti bo àwọn ọpọ́n méjì ìparí tí ń bẹ lókè àwọn ọ̀wọ́n; 43ẹsẹ̀ mẹ́wàá pẹ̀lú agbádá mẹ́wàá wọn; 44agbada ńlá náà, àti màlúù méjìlá tí ó wà lábẹ́ rẹ̀; 45ìkòkò, ọkọ́ àti àwokòtò.
Gbogbo ohun èlò wọ̀nyí tí Hiramu ṣe fún Solomoni ọba nítorí iṣẹ́ Olúwa sì jẹ́ idẹ dídán. 46Ọba sì dá wọn ní ilẹ̀ amọ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jordani lágbedeméjì Sukkoti àti Saretani.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.