Native Bible

1 Kings 7:43 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ẹsẹ̀ mẹ́wàá pẹ̀lú agbádá mẹ́wàá wọn;

1 Kings 7:43 in English

1 Kings 7:43 · Berean Standard Bible

the ten stands; the ten basins on the stands;

Context

41Àwọn ọ̀wọ́n méjì; ọpọ́n méjì ìparí tí ó wà lókè àwọn ọ̀wọ́n iṣẹ́; àwọn méjì ní láti bo ọpọ́n méjì ìparí tí ń bẹ lókè àwọn ọ̀wọ́n; 42irinwó (400) pomegiranate fún iṣẹ́ àwọn méjì, ọ̀wọ́ méjì pomegiranate fún iṣẹ́ àwọn kan láti bo àwọn ọpọ́n méjì ìparí tí ń bẹ lókè àwọn ọ̀wọ́n; 43ẹsẹ̀ mẹ́wàá pẹ̀lú agbádá mẹ́wàá wọn; 44agbada ńlá náà, àti màlúù méjìlá tí ó wà lábẹ́ rẹ̀; 45ìkòkò, ọkọ́ àti àwokòtò. Gbogbo ohun èlò wọ̀nyí tí Hiramu ṣe fún Solomoni ọba nítorí iṣẹ́ Olúwa sì jẹ́ idẹ dídán.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.