Native Bible

1 Kings 4:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Elihorefu àti Ahijah àwọn ọmọ Ṣisa akọ̀wé; Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni akọ̀wé ìlú;

1 Kings 4:3 in English

1 Kings 4:3 · Berean Standard Bible

Elihoreph and Ahijah, the sons of Shisha,* were secretaries; Jehoshaphat son of Ahilud was the recorder;

Context

1Solomoni ọba sì jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli. 2Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Asariah ọmọ Sadoku àlùfáà: 3Elihorefu àti Ahijah àwọn ọmọ Ṣisa akọ̀wé; Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni akọ̀wé ìlú; 4Benaiah ọmọ Jehoiada ni olórí ogun; Sadoku àti Abiatari ni àwọn àlùfáà; 5Asariah ọmọ Natani ni olórí àwọn agbègbè; Sabudu ọmọ Natani, àlùfáà àti olùgba ọba ní ìmọ̀ràn;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.