Native Bible

1 Kings 4:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Solomoni ọba sì jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli.

1 Kings 4:1 in English

1 Kings 4:1 · Berean Standard Bible

So King Solomon ruled over Israel,

Context

1Solomoni ọba sì jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli. 2Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Asariah ọmọ Sadoku àlùfáà: 3Elihorefu àti Ahijah àwọn ọmọ Ṣisa akọ̀wé; Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni akọ̀wé ìlú;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.