Native Bible

1 Kings 4:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Asariah ọmọ Sadoku àlùfáà:

1 Kings 4:2 in English

1 Kings 4:2 · Berean Standard Bible

and these were his chief officials: Azariah son of Zadok was the priest;

Context

1Solomoni ọba sì jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli. 2Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Asariah ọmọ Sadoku àlùfáà: 3Elihorefu àti Ahijah àwọn ọmọ Ṣisa akọ̀wé; Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni akọ̀wé ìlú; 4Benaiah ọmọ Jehoiada ni olórí ogun; Sadoku àti Abiatari ni àwọn àlùfáà;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.