Native Bible

1 Kings 4:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jehoṣafati ọmọ Parua ni ó wà ní Isakari;

1 Kings 4:17 in English

1 Kings 4:17 · Berean Standard Bible

Jehoshaphat son of Paruah in Issachar;

Context

15Ahimasi ní Naftali (ó fẹ́ Basemati ọmọbìnrin Solomoni ní aya). 16Baana ọmọ Huṣai ní Aṣeri àti ní Aloti; 17Jehoṣafati ọmọ Parua ni ó wà ní Isakari; 18Ṣimei ọmọ Ela ni Benjamini; 19Geberi ọmọ Uri ní Gileadi (orílẹ̀-èdè Sihoni ọba àwọn ará Amori àti orílẹ̀-èdè Ogu ọba Baṣani). Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.