Native Bible

1 Kings 4:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ahimasi ní Naftali (ó fẹ́ Basemati ọmọbìnrin Solomoni ní aya).

1 Kings 4:15 in English

1 Kings 4:15 · Berean Standard Bible

Ahimaaz in Naphtali (he had married Basemath, a daughter of Solomon);

Context

13Ọmọ Geberi ní Ramoti Gileadi (tirẹ̀ ni àwọn ìletò Jairi ọmọ Manase tí ń bẹ ní Gileadi, tirẹ̀ sì ni agbègbè Argobu, tí ń bẹ ní Baṣani, ọgọ́ta ìlú tí ó tóbi pẹ̀lú odi tí ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ irin). 14Ahinadabu ọmọ Iddo ní Mahanaimu 15Ahimasi ní Naftali (ó fẹ́ Basemati ọmọbìnrin Solomoni ní aya). 16Baana ọmọ Huṣai ní Aṣeri àti ní Aloti; 17Jehoṣafati ọmọ Parua ni ó wà ní Isakari;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.