Native Bible

1 Kings 4:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ahinadabu ọmọ Iddo ní Mahanaimu

1 Kings 4:14 in English

1 Kings 4:14 · Berean Standard Bible

Ahinadab son of Iddo in Mahanaim;

Context

12Baana ọmọ Ahiludi, ní Taanaki àti Megido, àti ní gbogbo Beti-Ṣeani tí ń bẹ níhà Saretani ní ìsàlẹ̀ Jesreeli, láti Beti-Ṣeani dé Abeli-Mehola títí dé ibi tí ń bẹ ní ìkọjá Jokimeamu. 13Ọmọ Geberi ní Ramoti Gileadi (tirẹ̀ ni àwọn ìletò Jairi ọmọ Manase tí ń bẹ ní Gileadi, tirẹ̀ sì ni agbègbè Argobu, tí ń bẹ ní Baṣani, ọgọ́ta ìlú tí ó tóbi pẹ̀lú odi tí ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ irin). 14Ahinadabu ọmọ Iddo ní Mahanaimu 15Ahimasi ní Naftali (ó fẹ́ Basemati ọmọbìnrin Solomoni ní aya). 16Baana ọmọ Huṣai ní Aṣeri àti ní Aloti;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.