Native Bible

1 Kings 4:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣimei ọmọ Ela ni Benjamini;

1 Kings 4:18 in English

1 Kings 4:18 · Berean Standard Bible

Shimei son of Ela in Benjamin;

Context

16Baana ọmọ Huṣai ní Aṣeri àti ní Aloti; 17Jehoṣafati ọmọ Parua ni ó wà ní Isakari; 18Ṣimei ọmọ Ela ni Benjamini; 19Geberi ọmọ Uri ní Gileadi (orílẹ̀-èdè Sihoni ọba àwọn ará Amori àti orílẹ̀-èdè Ogu ọba Baṣani). Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà. 20Àwọn ènìyàn Juda àti ti Israẹli pọ̀ gẹ́gẹ́ bí iyanrìn tí ń bẹ ní etí Òkun; wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu, wọ́n sì ń yọ ayọ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.