1 Kọrinti 16:21
1 Corinthians 16:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá.
1 Corinthians 16:21 in English
1 Corinthians 16:21 · Berean Standard Bible
This greeting is in my own hand—Paul.
Context
19Àwọn ìjọ ni Asia kí í yín.
Akuila àti Priskilla kí í yín púpọ̀ nínú Olúwa, pẹ̀lú ìjọ tí ó wà ni ilé wọn. 20Gbogbo àwọn arákùnrin kí í yín.
Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín. 21Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá. 22Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní ìfẹ́ Jesu Kristi Olúwa, jẹ́ kí ó dì ẹni ìfibú. Máa bọ Olúwa wa! 23Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa kí ó wà pẹ̀lú yín!
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.