1 Kọrinti 16:22
1 Corinthians 16:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní ìfẹ́ Jesu Kristi Olúwa, jẹ́ kí ó dì ẹni ìfibú. Máa bọ Olúwa wa!
1 Corinthians 16:22 in English
1 Corinthians 16:22 · Berean Standard Bible
If anyone does not love the Lord, let him be under a curse. Come, O Lord!*
Context
20Gbogbo àwọn arákùnrin kí í yín.
Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín. 21Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá. 22Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní ìfẹ́ Jesu Kristi Olúwa, jẹ́ kí ó dì ẹni ìfibú. Máa bọ Olúwa wa! 23Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa kí ó wà pẹ̀lú yín! 24Ìfẹ́ mi wá pẹ̀lú gbogbo yín nínú Kristi Jesu. Àmín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.