Native Bible

1 Corinthians 16:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa kí ó wà pẹ̀lú yín!

1 Corinthians 16:23 in English

1 Corinthians 16:23 · Berean Standard Bible

The grace of the Lord Jesus be with you.

Context

21Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá. 22Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní ìfẹ́ Jesu Kristi Olúwa, jẹ́ kí ó dì ẹni ìfibú. Máa bọ Olúwa wa! 23Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa kí ó wà pẹ̀lú yín! 24Ìfẹ́ mi wá pẹ̀lú gbogbo yín nínú Kristi Jesu. Àmín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.