Native Bible

1 Corinthians 16:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ìjọ ni Asia kí í yín. Akuila àti Priskilla kí í yín púpọ̀ nínú Olúwa, pẹ̀lú ìjọ tí ó wà ni ilé wọn.

1 Corinthians 16:19 in English

1 Corinthians 16:19 · Berean Standard Bible

The churches in the province of Asia * send you greetings. Aquila and Prisca * greet you warmly in the Lord, and so does the church that meets at their house.

Context

17Mo láyọ̀ fún wíwá Stefana àti Fortunatu àti Akaiku, nítorí èyí tí ó kù nípá tí yín wọ́n ti fi kún un. 18Nítorí tí wọ́n tu ẹ̀mí mí lára àti tiyín: nítorí náà, ẹ máa gba irú àwọn ti ó rí bẹ́ẹ̀. 19Àwọn ìjọ ni Asia kí í yín. Akuila àti Priskilla kí í yín púpọ̀ nínú Olúwa, pẹ̀lú ìjọ tí ó wà ni ilé wọn. 20Gbogbo àwọn arákùnrin kí í yín. Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín. 21Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.