1 Kọrinti 16:18
1 Corinthians 16:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí tí wọ́n tu ẹ̀mí mí lára àti tiyín: nítorí náà, ẹ máa gba irú àwọn ti ó rí bẹ́ẹ̀.
1 Corinthians 16:18 in English
1 Corinthians 16:18 · Berean Standard Bible
For they refreshed my spirit and yours as well. Show your appreciation, therefore, to such men.
Context
16Kí ẹ̀yin tẹríba fún irú àwọn báwọ̀nyí, àti fún olúkúlùkù olùbáṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú wa tí ó sì ń ṣe làálàá. 17Mo láyọ̀ fún wíwá Stefana àti Fortunatu àti Akaiku, nítorí èyí tí ó kù nípá tí yín wọ́n ti fi kún un. 18Nítorí tí wọ́n tu ẹ̀mí mí lára àti tiyín: nítorí náà, ẹ máa gba irú àwọn ti ó rí bẹ́ẹ̀. 19Àwọn ìjọ ni Asia kí í yín.
Akuila àti Priskilla kí í yín púpọ̀ nínú Olúwa, pẹ̀lú ìjọ tí ó wà ni ilé wọn. 20Gbogbo àwọn arákùnrin kí í yín.
Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.