1 Kronika 9:6
1 Chronicles 9:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní ti ará Sera: Jeueli. Àwọn ènìyàn láti Juda sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́wàá (690).
1 Chronicles 9:6 in English
1 Chronicles 9:6 · Berean Standard Bible
From the Zerahites: Jeuel and 690 relatives.
Context
4Uttai ọmọ Ammihudu, ọmọ Omri, ọmọ Imri, ọmọ Bani, ìran ọmọ Peresi ọmọ Juda. 5Àti nínú ará Ṣilo:
Asaiah àkọ́bí àti àwọn ọmọ rẹ̀. 6Ní ti ará Sera:
Jeueli.
Àwọn ènìyàn láti Juda sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́wàá (690). 7Àti nínú àwọn ọmọ Benjamini ni:
Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah; ọmọ Hasenuah; 8Ibinaiah ọmọ Jerohamu;
Ela ọmọ Ussi, ọmọ Mikri;
àti Meṣullamu ọmọ Ṣefatia; ọmọ Reueli, ọmọ Ibinijah.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.