1 Kronika 9:5
1 Chronicles 9:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àti nínú ará Ṣilo: Asaiah àkọ́bí àti àwọn ọmọ rẹ̀.
1 Chronicles 9:5 in English
1 Chronicles 9:5 · Berean Standard Bible
From the Shilonites: Asaiah the firstborn and his sons.
Context
3Àwọn tí ó wá láti Juda láti Benjamini àti láti Efraimu àti Manase tí ó ń gbé ní Jerusalẹmu jẹ́: 4Uttai ọmọ Ammihudu, ọmọ Omri, ọmọ Imri, ọmọ Bani, ìran ọmọ Peresi ọmọ Juda. 5Àti nínú ará Ṣilo:
Asaiah àkọ́bí àti àwọn ọmọ rẹ̀. 6Ní ti ará Sera:
Jeueli.
Àwọn ènìyàn láti Juda sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́wàá (690). 7Àti nínú àwọn ọmọ Benjamini ni:
Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah; ọmọ Hasenuah;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.