1 Kronika 9:8
1 Chronicles 9:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ibinaiah ọmọ Jerohamu; Ela ọmọ Ussi, ọmọ Mikri; àti Meṣullamu ọmọ Ṣefatia; ọmọ Reueli, ọmọ Ibinijah.
1 Chronicles 9:8 in English
1 Chronicles 9:8 · Berean Standard Bible
Ibneiah son of Jeroham; Elah son of Uzzi, the son of Michri; Meshullam son of Shephatiah, the son of Reuel, the son of Ibnijah;
Context
6Ní ti ará Sera:
Jeueli.
Àwọn ènìyàn láti Juda sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́wàá (690). 7Àti nínú àwọn ọmọ Benjamini ni:
Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah; ọmọ Hasenuah; 8Ibinaiah ọmọ Jerohamu;
Ela ọmọ Ussi, ọmọ Mikri;
àti Meṣullamu ọmọ Ṣefatia; ọmọ Reueli, ọmọ Ibinijah. 9Àwọn ènìyàn láti Benjamini gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe kọ ọ́ nínú ìran wọn nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó dín mẹ́rìnlélógójì (956). Gbogbo àwọn ọkùnrin yí jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé. 10Ní ti àwọn àlùfáà:
Jedaiah; Jehoiaribi; Jakini;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.