Native Bible

1 Chronicles 9:40 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika.

1 Chronicles 9:40 in English

1 Chronicles 9:40 · Berean Standard Bible

The son of Jonathan: Merib-baal, who was the father of Micah.

Context

38Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 39Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali. 40Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika. 41Àwọn ọmọ Mika: Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi. 42Ahasi jẹ́ baba Jada, Jada jẹ́ baba Alemeti, Asmafeti, Simri, sì Simri jẹ́ baba Mosa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.