Native Bible

1 Chronicles 9:38 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu.

1 Chronicles 9:38 in English

1 Chronicles 9:38 · Berean Standard Bible

Mikloth was the father of Shimeam.* They too lived alongside their relatives in Jerusalem.

Context

36pẹ̀lú àkọ́bí ọmọkùnrin rẹ̀ jẹ́ Abdoni, tí wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu. 37Gedori, Ahio, Sekariah àti Mikiloti. 38Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 39Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali. 40Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.