Native Bible

1 Chronicles 9:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Gedori, Ahio, Sekariah àti Mikiloti.

1 Chronicles 9:37 in English

1 Chronicles 9:37 · Berean Standard Bible

Gedor, Ahio, Zechariah, and Mikloth.

Context

35Jeieli baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni. Orúkọ ìyàwó rẹ̀ a máa jẹ́ Maaka, 36pẹ̀lú àkọ́bí ọmọkùnrin rẹ̀ jẹ́ Abdoni, tí wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu. 37Gedori, Ahio, Sekariah àti Mikiloti. 38Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 39Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.