Native Bible

1 Chronicles 9:39 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali.

1 Chronicles 9:39 in English

1 Chronicles 9:39 · Berean Standard Bible

Ner was the father of Kish, Kish was the father of Saul, and Saul was the father of Jonathan, Malchishua, Abinadab, and Esh-baal.

Context

37Gedori, Ahio, Sekariah àti Mikiloti. 38Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 39Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali. 40Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika. 41Àwọn ọmọ Mika: Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.