Native Bible

1 Chronicles 9:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ahasi jẹ́ baba Jada, Jada jẹ́ baba Alemeti, Asmafeti, Simri, sì Simri jẹ́ baba Mosa.

1 Chronicles 9:42 in English

1 Chronicles 9:42 · Berean Standard Bible

Ahaz was the father of Jarah; Jarah * was the father of Alemeth, Azmaveth, and Zimri; and Zimri was the father of Moza.

Context

40Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika. 41Àwọn ọmọ Mika: Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi. 42Ahasi jẹ́ baba Jada, Jada jẹ́ baba Alemeti, Asmafeti, Simri, sì Simri jẹ́ baba Mosa. 43Mosa jẹ́ baba Binea; Refaiah jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀. 44Aseli ní ọmọ mẹ́fà, pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli Ṣeariah, Obadiah àti Hanani, gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.