1 Kronika 9:43
1 Chronicles 9:43 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Mosa jẹ́ baba Binea; Refaiah jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀.
1 Chronicles 9:43 in English
1 Chronicles 9:43 · Berean Standard Bible
Moza was the father of Binea. Rephaiah * was his son, Elasah his son, and Azel his son.
Context
41Àwọn ọmọ Mika:
Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi. 42Ahasi jẹ́ baba Jada, Jada jẹ́ baba Alemeti, Asmafeti, Simri, sì Simri jẹ́ baba Mosa. 43Mosa jẹ́ baba Binea; Refaiah jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀. 44Aseli ní ọmọ mẹ́fà, pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn:
Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli Ṣeariah, Obadiah àti Hanani, gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.