1 Kronika 8:29
1 Chronicles 8:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni. Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka,
1 Chronicles 8:29 in English
1 Chronicles 8:29 · Berean Standard Bible
Jeiel the father of Gibeon lived * in Gibeon. His wife’s name was Maacah,
Context
27Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu. 28Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu. 29Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni.
Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka, 30àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ Abdoni wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu, 31Gedori Ahio, Sekeri
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.