1 Kronika 8:28
1 Chronicles 8:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu.
1 Chronicles 8:28 in English
1 Chronicles 8:28 · Berean Standard Bible
All these were heads of families, the chiefs according to their genealogies, and they lived in Jerusalem.
Context
26Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah 27Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu. 28Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu. 29Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni.
Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka, 30àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ Abdoni wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.