Native Bible

1 Chronicles 8:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu.

1 Chronicles 8:27 in English

1 Chronicles 8:27 · Berean Standard Bible

Jaareshiah, Elijah, and Zichri were the sons of Jeroham.

Context

25Ifediah àti Penueli jẹ́ àwọn ọmọ Ṣasaki. 26Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah 27Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu. 28Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu. 29Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni. Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.