Native Bible

1 Chronicles 8:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ahio, Ṣasaki, Jeremoti,

1 Chronicles 8:14 in English

Context

12Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.) 13Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò. 14Ahio, Ṣasaki, Jeremoti, 15Sebadiah, Aradi, Ederi 16Mikaeli, Iṣifa àti Joha jẹ́ àwọn ọmọ Beriah.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.