1 Kronika 8:13
1 Chronicles 8:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò.
1 Chronicles 8:13 in English
1 Chronicles 8:13 · Berean Standard Bible
and Beriah and Shema (who were the heads of families of the inhabitants of Aijalon and who drove out the inhabitants of Gath).
Context
11Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali. 12Àwọn ọmọ Elipali:
Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.) 13Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò. 14Ahio, Ṣasaki, Jeremoti, 15Sebadiah, Aradi, Ederi
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.