Native Bible

1 Chronicles 8:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali.

1 Chronicles 8:11 in English

1 Chronicles 8:11 · Berean Standard Bible

He also had sons by Hushim: Abitub and Elpaal.

Context

9Nípasẹ̀ ìyàwó rẹ̀ Hodeṣi ó ní Jobabu Sibia, Meṣa, Malkamu, 10Jeusi, Sakia àti Mirma. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé. 11Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali. 12Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.) 13Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.