Native Bible

1 Chronicles 8:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.)

1 Chronicles 8:12 in English

1 Chronicles 8:12 · Berean Standard Bible

The sons of Elpaal: Eber, Misham, Shemed (who built Ono and Lod with its villages),

Context

10Jeusi, Sakia àti Mirma. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé. 11Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali. 12Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.) 13Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò. 14Ahio, Ṣasaki, Jeremoti,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.