1 Kronika 5:12
1 Chronicles 5:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Joẹli jẹ́ olórí, Ṣafamu ìran ọmọ Janai, àti Ṣafati ni Baṣani.
1 Chronicles 5:12 in English
1 Chronicles 5:12 · Berean Standard Bible
Joel was the chief, Shapham the second, then Jaanai and Shaphat, who lived in Bashan.
Context
10Àti ní ọjọ́ Saulu, wọ́n bá àwọn ọmọ Hagari jagun, ẹni tí ó ṣubú nípa ọwọ́ wọn; wọ́n sì ń gbé inú àgọ́ wọn ní gbogbo ilẹ̀ àríwá Gileadi. 11Àti àwọn ọmọ Gadi ń gbé lékè wọn, ní ilẹ̀ Baṣani títí dé Saleka: 12Joẹli jẹ́ olórí, Ṣafamu ìran ọmọ Janai, àti Ṣafati ni Baṣani. 13Àti àwọn arákùnrin wọn ti ilẹ̀ àwọn baba wọn ní:
Mikaeli, Meṣullamu Ṣeba, Jorai, Jaka, Sia àti Eberi méje. 14Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Abihaili, ọmọ Huri, ọmọ Jeroa, ọmọ Gileadi, ọmọ Mikaeli, ọmọ Jeṣiṣai, ọmọ Jado, ọmọ Busi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.