1 Kronika 5:13
1 Chronicles 5:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àti àwọn arákùnrin wọn ti ilẹ̀ àwọn baba wọn ní: Mikaeli, Meṣullamu Ṣeba, Jorai, Jaka, Sia àti Eberi méje.
1 Chronicles 5:13 in English
1 Chronicles 5:13 · Berean Standard Bible
Their kinsmen by families were Michael, Meshullam, Sheba, Jorai, Jacan, Zia, and Eber—seven in all.
Context
11Àti àwọn ọmọ Gadi ń gbé lékè wọn, ní ilẹ̀ Baṣani títí dé Saleka: 12Joẹli jẹ́ olórí, Ṣafamu ìran ọmọ Janai, àti Ṣafati ni Baṣani. 13Àti àwọn arákùnrin wọn ti ilẹ̀ àwọn baba wọn ní:
Mikaeli, Meṣullamu Ṣeba, Jorai, Jaka, Sia àti Eberi méje. 14Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Abihaili, ọmọ Huri, ọmọ Jeroa, ọmọ Gileadi, ọmọ Mikaeli, ọmọ Jeṣiṣai, ọmọ Jado, ọmọ Busi. 15Ahi, ọmọ Adbeeli, ọmọ Guni, olórí ilé àwọn baba wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.