1 Kronika 5:15
1 Chronicles 5:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ahi, ọmọ Adbeeli, ọmọ Guni, olórí ilé àwọn baba wọn.
1 Chronicles 5:15 in English
1 Chronicles 5:15 · Berean Standard Bible
Ahi son of Abdiel, the son of Guni, was head of their family.
Context
13Àti àwọn arákùnrin wọn ti ilẹ̀ àwọn baba wọn ní:
Mikaeli, Meṣullamu Ṣeba, Jorai, Jaka, Sia àti Eberi méje. 14Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Abihaili, ọmọ Huri, ọmọ Jeroa, ọmọ Gileadi, ọmọ Mikaeli, ọmọ Jeṣiṣai, ọmọ Jado, ọmọ Busi. 15Ahi, ọmọ Adbeeli, ọmọ Guni, olórí ilé àwọn baba wọn. 16Wọ́n sì ń gbé Gileadi ní Baṣani àti nínú àwọn ìlú rẹ̀, àti nínú gbogbo ìgbèríko Ṣaroni, ní agbègbè wọn. 17Gbogbo wọ̀nyí ni a kà nípa ìtàn ìdílé, ní ọjọ́ Jotamu ọba Juda, àti ní ọjọ́ Jeroboamu ọba Israẹli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.