Native Bible

1 Chronicles 4:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n sì ń gbé ní Beerṣeba, Molada, Hasari-Ṣuali,

1 Chronicles 4:28 in English

1 Chronicles 4:28 · Berean Standard Bible

They lived in Beersheba, Moladah, Hazar-shual,

Context

26Àwọn ọmọ Miṣima: Hamueli ọmọ rẹ̀ Sakkuri ọmọ rẹ̀ àti Ṣimei ọmọ rẹ̀. 27Ṣimei sì ní ọmọkùnrin mẹ́rìndínlógún àti ọmọbìnrin mẹ́fà, ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin kò ní ọmọ púpọ̀; bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìdílé wọn kò sì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn Juda. 28Wọ́n sì ń gbé ní Beerṣeba, Molada, Hasari-Ṣuali, 29àti ní Biliha, àti ní Esemu, àti ní Toladi, 30Betueli, Horma, Siklagi,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.