Native Bible

1 Chronicles 4:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

àti ní Biliha, àti ní Esemu, àti ní Toladi,

1 Chronicles 4:29 in English

Context

27Ṣimei sì ní ọmọkùnrin mẹ́rìndínlógún àti ọmọbìnrin mẹ́fà, ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin kò ní ọmọ púpọ̀; bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìdílé wọn kò sì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn Juda. 28Wọ́n sì ń gbé ní Beerṣeba, Molada, Hasari-Ṣuali, 29àti ní Biliha, àti ní Esemu, àti ní Toladi, 30Betueli, Horma, Siklagi, 31Beti-Markaboti Hormah; Hasari Susimu, Beti-Biri àti Ṣaraimi. Àwọn wọ̀nyí ni ìlú wọn títí di ìgbà ọba Dafidi,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.