1 Kronika 4:26
1 Chronicles 4:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Miṣima: Hamueli ọmọ rẹ̀ Sakkuri ọmọ rẹ̀ àti Ṣimei ọmọ rẹ̀.
1 Chronicles 4:26 in English
1 Chronicles 4:26 · Berean Standard Bible
The sons of Mishma: Hammuel, Zaccur, and Shimei.
Context
24Àwọn ọmọ Simeoni:
Nemueli, Jamini, Jaribi, Sera àti Saulu; 25Ṣallumu sì jẹ́ ọmọ Saulu, Mibsamu ọmọ rẹ̀ Miṣima ọmọ rẹ̀. 26Àwọn ọmọ Miṣima:
Hamueli ọmọ rẹ̀ Sakkuri ọmọ rẹ̀ àti Ṣimei ọmọ rẹ̀. 27Ṣimei sì ní ọmọkùnrin mẹ́rìndínlógún àti ọmọbìnrin mẹ́fà, ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin kò ní ọmọ púpọ̀; bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìdílé wọn kò sì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn Juda. 28Wọ́n sì ń gbé ní Beerṣeba, Molada, Hasari-Ṣuali,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.