Native Bible

1 Chronicles 4:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Simeoni: Nemueli, Jamini, Jaribi, Sera àti Saulu;

1 Chronicles 4:24 in English

1 Chronicles 4:24 · Berean Standard Bible

The descendants of Simeon: Nemuel, Jamin, Jarib, Zerah,* and Shaul.

Context

22Jokimu, ọkùnrin Koseba, àti Joaṣi àti Sarafi, olórí ní Moabu àti Jaṣubi Lehemu. (Àkọsílẹ̀ yìí sì wà láti ìgbà àtijọ́.) 23Àwọn sì ni amọ̀kòkò tí ń gbé ní Netaimu àti Gedera; wọ́n sì dúró níbẹ̀ wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ fún ọba. 24Àwọn ọmọ Simeoni: Nemueli, Jamini, Jaribi, Sera àti Saulu; 25Ṣallumu sì jẹ́ ọmọ Saulu, Mibsamu ọmọ rẹ̀ Miṣima ọmọ rẹ̀. 26Àwọn ọmọ Miṣima: Hamueli ọmọ rẹ̀ Sakkuri ọmọ rẹ̀ àti Ṣimei ọmọ rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.