1 Kronika 4:16
1 Chronicles 4:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Jehaleeli: Sifi, àti Sifa, Tiria àti Asareeli.
1 Chronicles 4:16 in English
1 Chronicles 4:16 · Berean Standard Bible
The sons of Jehallelel: Ziph, Ziphah, Tiria, and Asarel.
Context
14Meonotai sì ni baba Ofira.
Seraiah sì jẹ́ baba Joabu,
baba Geharaṣinu. A pè báyìí nítorí àwọn ènìyàn àwọn oníṣọ̀nà ní ìwọ̀n. 15Àwọn ọmọ Kalebu ọmọ Jefunne:
Iru, Ela, àti Naamu.
Àwọn ọmọ Ela:
Kenasi. 16Àwọn ọmọ Jehaleeli:
Sifi, àti Sifa, Tiria àti Asareeli. 17Àwọn ọmọ Esra:
Jeteri, Meredi, Eferi àti Jaloni.
Ọ̀kan lára àwọn aya Meredi sì bí Miriamu, Ṣammai àti Iṣba baba Eṣitemoa. 18Aya rẹ̀ láti ẹ̀yà Juda sì bí Jaredi baba Gedori, àti Heberi baba Soko àti Jekutieli baba Sanoa. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin Farao Bitia, ẹni ti Meredi ti fẹ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.