1 Kronika 4:15
1 Chronicles 4:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Kalebu ọmọ Jefunne: Iru, Ela, àti Naamu. Àwọn ọmọ Ela: Kenasi.
1 Chronicles 4:15 in English
1 Chronicles 4:15 · Berean Standard Bible
The sons of Caleb son of Jephunneh: Iru, Elah, and Naam. The son * of Elah: Kenaz.
Context
13Àwọn ọmọ Kenasi:
Otnieli àti Seraiah.
Àwọn ọmọ Otnieli:
Hatati àti Meonotai. 14Meonotai sì ni baba Ofira.
Seraiah sì jẹ́ baba Joabu,
baba Geharaṣinu. A pè báyìí nítorí àwọn ènìyàn àwọn oníṣọ̀nà ní ìwọ̀n. 15Àwọn ọmọ Kalebu ọmọ Jefunne:
Iru, Ela, àti Naamu.
Àwọn ọmọ Ela:
Kenasi. 16Àwọn ọmọ Jehaleeli:
Sifi, àti Sifa, Tiria àti Asareeli. 17Àwọn ọmọ Esra:
Jeteri, Meredi, Eferi àti Jaloni.
Ọ̀kan lára àwọn aya Meredi sì bí Miriamu, Ṣammai àti Iṣba baba Eṣitemoa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.